Create your own games

GDevelop game maker software - create video games without coding

GDevelop jẹ́ ètò orísun-gbangba kan fún ṣíṣẹ̀dá eré lórí èyíkéyìí ètò, tí a ṣe láti jẹ́ lílò fún gbogbo èèyàn - kò nílò àwọn ìmọ̀ nípa èdè kọ̀mpútà.

Ṣẹ̀dá èyíkéyìí eré

Unleash your creativity with GDevelop and create any kind of game: platformers, puzzles, shoot 'em up, strategy, 8-bit games... Go through the examples or start a new project from scratch.

With GDevelop, you can make simple projects for fun or create ambitious indie games like Lil BUB's HELLO EARTH, Hyperspace Dogfights and tons of other games!

Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ - ṣíṣẹ̀dá eré fún gbogbo èèyàn

Nnkan tó mú GDevelop yàtọ̀ àti rọrùn láti lò ní àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ náà. Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ jẹ́ ọ̀nà pàtàkì kan láti ṣàlàyé ìlànà eré rẹ, láì nílò láti kẹ́kọ̀ọ́ nípa èdè kọ̀mpútà.

Events enable easy game creation

Nígbà tí Àlàfo bá gba títẹ̀, àwòrán abẹ̀mí òṣèré náà àti ohùn kan ma bẹ̀rẹ̀. Tí bọ́ǹbù kan bá kàn òṣèré náà, àwọn méjèèjì ma parun.

Ṣàgbéjáde eré rẹ ní títẹ̀ kan

Publish your games to the web, iOS, Android, Windows, Mac, Linux and even Facebook Messenger. Games created with GDevelop run anywhere and you can even do a one-click export to Android from the app.

Make games for iOS, Android, Windows, macOS and Linux

Unlimited possibilities

Express your ideas without being blocked: you can prototype new features on your games in minutes, and refine them without limits. Making games has never been as easy as assembling your ideas with the visual editors provided by GDevelop. Want to go even further? You can extend the game engine with Javascript.

See how to add a trigger button to your platformer game in 90 seconds

Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú àwọn àlàyé

Learn step-by-step how to use GDevelop or get help about a specific feature: the wiki has tutorials for beginners and a complete documentation for the software. Tons of examples are also available and ready to be tried in one click.

Àwọn àlàyé fún GDevelop àti àkọsílẹ̀ lórí wiki náà

Start making games

Gbèrò nípa kí o sì ṣàtẹ̀jáde àwọn eré rẹ pẹ̀lú GDevelop. Tí a kójọ pọ̀ pẹ̀lú àwọn àlàyé àti àwọn àpẹẹrẹ.

GDevelop jẹ́ ètò orísun-gbangba kan fún ṣíṣẹ̀dá eré. Ó lè jẹ́ lílò nípasẹ̀ ẹnikẹ́ni láti ṣẹ̀dá èyíkéyìí irú àwọn eré 2D.

GDevelop gba ṣíṣẹ̀dá pẹ̀lú ìfẹ́ nípasẹ̀ Florian Rival

Ọpẹ́lọpẹ́ àwọn olùdásí tó ṣàfikún àwọn ẹyà, ṣàtúnṣe àwọn ìyọnu, fi àwọn àpẹẹrẹ tuntun ránṣẹ́, kọ àwọn àlàyé, àti ran àwùjọ náà lọ́wọ́.